CAC HB Yoruba Hymn 1

2 years ago prayertitus 0
1 Ago re wonni ti ni e wa to. Oluwa awon omo ogun. OD.84:1 CM
1 “””Olu s`agun tan e ni re
Fi ara re han wa
Bo ti fun wa nile adua
Mokan wa gbadura”””
2 “Fi ami ife re han wa
So ireti wa ji
Se ri bukun re sori wa
Ka wa le ma yin O”
3 “Ki fe ati alafia
Ko ma gbe ile yi Fi ro ra fokan iponju
M okan ailera le .”
4 “””Fe ti igbo aya igbase
Oju riran fun wa
Tan imole re l`atoke Ka dagba l`o re ofe “
5 “””Ka fi gbagba gb oro re
Ka fi gba gbo bebe
A ti niwaju Oluwa
Ka se aroye wa. Amin ”
Click below banner for quick download

Download now (quick server)
Check:  No fear lyrics by Kaytez Kanu